Adolf Hitler (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈadɔlf ˈhɪtlɐ]; 20 April 1889 – 30 April 1945) je omo Jemani ti a bi ni Austria to je oloselu ati olori Egbe awon Osise Sosialisti Tomoorile-ede Jemani (, kikekuru bi NSDAP), to gbajumo bi Egbe Nazi. O je Kansilo ile Jemani lati 1933 de 1945 besini leyin 1934, gege bi olori orile-ede bi Führer und Reichskanzler, o si joba ibe bi apase wa.

Adolf Hitler
20 April 1937 (48th Birthday)
Führer of Germany
In office
2 August 1934 – 30 April 1945
Asíwájú Paul von Hindenburg
(as President)
Arọ́pò Karl Dönitz
(as President)
Reichskanzler (Chancellor) of Germany
In office
30 January 1933 – 30 April 1945
Asíwájú Kurt von Schleicher
Arọ́pò Joseph Goebbels
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí 20 April 1889
Braunau am Inn, Austria–Hungary
Aláìsí 30 April 1945(1945-04-30) (ọmọ ọdún 56)
Berlin, Germany
Cause of death Suicide
Aráàlú Austrian (1889–1932)
German (1932–1945)
Ọmọorílẹ̀-èdè Austrian citizen until 1925[1] German citizen after 1932
Ẹgbẹ́ olóṣèlú National Socialist German Workers Party (NSDAP)
(Àwọn) olólùfẹ́ Eva Braun
(married on 29 April 1945)
Occupation politician, soldier, artist, writer
Awards Iron Cross First and Second Class
Wound Badge
Signature
Military service
Allegiance German Empire German Empire
Branch/service Reichsheer
Years of service 1914–1918
Rank Gefreiter
Unit 16th Bavarian Reserve Regiment
Battles/wars World War I


Itokasi àtúnṣe

  1. "Hitler ersucht um Entlassung aus der österreichischen Staatsangehörigkeit", 7 April 1925 (Jẹ́mánì). Translation: "Hitler's official application to end his Austrian citizenship". NS-Archiv. Retrieved on 2008-08-19