BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
-
Wo ìdí tí ìdìtẹ̀gbàjọba míràn ko fi leè wáyé ni Nàíjíríà
Ọpọ ọmọ orilẹ ede Naijiria ko dunnu si ọwọ ti wọn fi n mu ijọba tiwa n tiwa.
-
Ìwọ́de 'Ẹnúgbẹ' wáyé ní Oyo, Osun, Eko - Ọlọ́pàá kó àwọn olùwọ́de nílùú Ibadan
Ileeṣẹ ọlọpaa ati DSS ti ke si awọn olori ẹka rẹ kaakiri Naijiria lati ri daju pe idarudapọ kankan ko waye lasiko iwọde naa ti yoo waye lonii ‘June 12.’
-
Ààrẹ Tinubu ṣubú níbi àyájọ́ ìjọba àwarawa June 12 nílùú Abuja
Akọroyin BBC to wa ni gbongan Eagles Square ni kete ti Aarẹ subu ni awọn ẹsọ alabo to wa ni ayika Aarẹ suure lati fa Aarẹ dide.
-
Aunty Ramota bọ́ síta sọ̀rọ̀ lẹ́yìn awuyewuye pé ó fọn ìdí
Ramota ninu fọnran tuntun to gbe sori Ayelujara, dupẹ lọwọ awọn ololufẹ rẹ fun bi wọn karamaasiki rẹ.
-
Wo kókó ọ̀rọ̀ tí Ààrẹ Bola Tinubu báwọn ọmọ Nàíjíríà sọ ní àyájọ́ ìjọba àwaarawa
Aarẹ Bola Tinubu bawọn ọmọ Naijiria sọrọ lati ki wọn ku orire ayajọ ijọba awarawa ti ọdun 2024, ti ọpọ eeyan mọ si June 12.
-
Mọ̀lẹ́bí sọ̀rọ̀ lórí ikú tó pa Sule Suebebe lẹ́yìn tó dé ọ̀dọ̀ Pásítọ̀ Agbala Gabriel
Iroyin nipa iku agba oṣere tiata naa ni agbajugbaja pasitọ, Gabriel Ademola Amusan ti fidi rẹ mulẹ lori opo ayelujara rẹ.
-
June 12: Ọjọ́ tí ọ̀pọ̀ ẹ̀yà, èdè àti ẹlẹ́sìnjẹ̀sìn ní Nàíjíríà papọ̀ di ọ̀kan
Ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹfà ọdún 1993, tá a mọ̀ sí ‘June 12’, ni ìbò ààrẹ wáyé àmọ́ tí wọn kò kéde ẹni tó jáwé olúborí nínú ìbò náà.
-
Kọ́lẹ́rà bẹ́ sílẹ̀ l‘Eko, èèyàn márùn-ún kú, ọgọ́ta wà ní ilé ìwòsàn
Kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera, Ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Abayomi tó kéde ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ Eti-Osa, Lagos Island, Ikorodu àti Kosofe ni àìsàn náà ti gbilẹ̀.
-
Wo àwọn nǹkan tó yẹ kó o mọ̀ nípa Saulos Chilima, igbákejì ààrẹ Malawi tó jáde láyé lẹ́ni ọdún 51
Saualos Chilima ati awọn mẹsan-an mii towa ninu baalu ile isẹ Ologun tilẹ Malawi ya bara kuro loju ọna rẹ ni owurọ ana.
-
Wo ọ̀pọ̀ ewu tó rọ̀ mọ́ ìdí fífọn àti ọ̀nà tó ń gbà mú ẹ̀mí lọ
Awọn eeyan maa n tipasẹ iṣẹ abẹ idi fifọn padanu ẹmi wọn nitori bi wọn ti ko ọra kuro ninu ara lọ si inu iṣan to tobi ti yoo si gba ibẹ lọ si awọn ẹya ara miran.
-
‘Ẹ̀mí èèyàn kò níyì mọ́ níbí torí ìbálòpọ̀ àti ìpànìyàn ti di gbẹ̀fẹ́’
Akọwe ẹgbẹ awọn agbẹjọro lagbegbe Dafur, Sadiq Hassan ni ọọdunrun eeyan lo ti ku lagbegbe naa bo tilẹ jẹ pe ijọba sọ pe idaji iye naa lo tii ku.
-
Wo orin ìbílẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá tí Awolowo gbé kalẹ̀, táwọn Gómìnà fòǹtẹ̀ lù
Agba ọjẹ ninu oṣelu ati olori iwọ oorun nigba kan ri lorilẹede Naijiria, Oloye Obafemi Awolowo lo ṣe ẹ̀dá orin naa ni ọdun 1978 nigba to da ẹgbẹ oṣelu UPN silẹ.
Ìròyìn Àkàgbádùn
-
Bàálù tó gbé igbákejì ààrẹ Malawi, di àwátì lójú òfurufú
Bàálù tó gbé igbákejì ààrẹ Malawi àti àwọn mẹ́sàn-àn míì di àwátì
-
Fídíò, Ọdún 1996 ni Aládùúrà ti sọtẹ́lẹ̀ pé màá jọba, tó sì wá sí ìmúṣẹDuration, 5,01
Aseyin ti Iseyin ráwọ́ ẹ̀bẹ̀ pé káwọn èèyàn forí jin Olusegun Obasanjo lórí àbùkù "Ẹ dìde, ẹ jókòó" tó ṣe sáwọn ọba aláyé.
-
Ikú òṣèré tó rì sínú omi jẹ́ kí Nollywood mójútó ètò ààbò òṣèré
Junior Pope, tii se gbajumọ osere tiata jade laye losu kẹrin ọdun 2024 lasiko ti ọkọ oju omi to wọ nigba ti wọn n ya sinima rì sinu odo Niger.
-
Àwọn aṣòfin dábàá ṣáà ọlọ́dún mẹ́fà fún ààrẹ àti àwọn gómìnà
gbakeji aarẹ akọkọ ni yoo dabi adele, o si gbọdọ wa lati ẹkùn kan naa pẹlu aarẹ. Oun ni yoo si rọpo aarẹ ti ko ba l'agbara lati ṣe ijọba mọ.
-
Ṣé lóòtọ́ọ́ ni Fadá ìjọ Aguda ṣe ìyàwó pẹ̀lú ọ̀rẹ́bìnrin rẹ? Ohun tí a mọ̀ rèé
Iroyin kan to jade lo sọ pe Fada Jude Obasi ni oun ko ni igbagbọ ninu igbe-aye ẹtan ti ọpọ alufaa n gbe.
-
₦62,000 tí ìjọba fi lọ̀ wá kò tẹ́ wa lọ́rùn, a kò fẹ́ ₦100,000, ₦250,000 ni a fẹ́ – NLC/TUC
Lọjọ Aje ni ọọfisi akọwe ijọba apapọ jabọ pe igbimọ to n jiroro lori ọrọ owo oṣu oṣiṣẹ to kere julọ naa ti jabọ ijiroro rẹ fun ijọba.
-
Tinubu jèrè inú rere mi, ni àga gómìnà Eko kò ṣe gbóná mọ́ ọ nídìí - Atiku
Ninu ifesi ti Atiku fi lede nipasẹ agbẹnusọ iroyin rẹ, Paul Ibe, O tọka sii pe irọ ni ọrọ ti shetiima sọ, ati wipe Aarẹ Tinubu gan lo jẹ anfaani inu re ohun lagbo oselu
-
Bí EFCC ṣe ń kó àwọn èèyàn sí àhámọ́ lọ́nà àìtọ́ tako ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn - Àwọn ọ̀dọ́ yarí
Ọpọ awọn to n gbero lati ṣe iwọde yii lo ti n pin fọto kaakiri ori ayelujara nipa akoko ati ibi ti wọn fẹ lo fun iwọde ọhun.
-
Mọ nípa àwọn oúnjẹ aṣara lóore tó lè dènà ìgbẹ́ gbuuru fún ọmọ rẹ
Iwadii naa sọ pe awọn ipinlẹ Borno, Bauchi, Zamfara, Kano, Kebbi ati Sokoto wa lara awọn ipinlẹ ti afikun ti de ba iye awọn ọmọde to n laiṣan igbẹ gbuuru lorilẹede Naijiria.
-
Ìjọba Egypt yọ owó ìránwọ́ orí búrẹ́dì, aráàlú yarí
Owo iranwọ ori burẹdi naa wa lara awọn owo ti ijọba n na julọ ninu eto iṣuna rẹ paapaa laarin ọdun 2016 si 2020.
-
Wo òfin tí ìjọba Tinubu fẹ́ gbé kalẹ̀ lórí àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin tó ń sun ilé ìtura ní Nàìjíríà
Minisita fọrọ awọn obinrin ni igbesẹ yii da lori igbiyanju ìjọba apapọ lati gbe ogun ti owo karakata awọn ọdọ ọmọbìnrin to wọpọ bayii.
-
Makinde sọ̀rọ̀ nípa ìgbà tí ayẹyẹ ìfinijoyè Ọba Olakulehin yóò wáyé gẹ́gẹ́ bí Olubadan tuntun
Ṣaaju ni igbimọ afọbajẹ Olubadan ilẹ Ibadan ti kede Ọba Olakulehin gẹgẹ bii Olubadan ikẹtalelogoji nilẹ Ibadan.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Móríwú
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
-
Wo bí wọ́n ṣe máa ń sin òkú àwọn arìnrìnàjò Hajj tó bá kú sí Mecca
Lasiko eto Hajj ọdun 2015, eeyan to le ni ẹgbẹrun meji lo ku ninu awọn arinrin-ajo Hajj lẹyin t'awọn oniṣẹ Hajj tẹ wọn pa.
-
'Mo fẹ́ẹ̀ yìnbọn pa ìyàwó mi nígbà tí mo gbọ́ pé ọmọ mẹ́ta tó bí fún mi kìí ṣe tèmi'
Ninu ifọrọwerọ kan laipẹ yii ni Lamptey ti sọ pe ọrọ naa dun oun to bẹẹ gẹ ti oun fẹ ṣina ibon bolẹ fun obinrin naa.
-
Èèyàn 150 tí wọ́n tún pa lábúlé kan ní Sudan di ariwo làgbàáyé
Ni bayii, o ti to ẹgbẹrun mẹẹẹdogun eeyan (15,000) ti akọsilẹ fi han pe wọn ti pa latigba ti ogun ti bẹrẹ loṣu kẹrin ọdun 2023.
-
Ẹ̀rí tuntun jáde nípa nǹkan tó ṣeéṣe kó pa Mohbad
Awọn nnkan to yẹ ki o mọ nipa nnkan ti awọn onimọ ilera sọ nipa iku Mohbad
-
Ṣé lóòtọ́ ni ìjọba yóò san N105,000 gẹ́gẹ́ bíi owó oṣù tuntun? - Iléeṣẹ́ Ààrẹ ṣàlàyé
Wale Edun tẹ́ pẹpẹ ọ̀rọ̀ owó osù òsìsẹ́ tuntun síwájú ààrẹ Tinubu.
-
Àdó olóró Israel balẹ̀ sílé ẹ̀kọ́ ní Gaza, èèyàn 35 kú, ọ̀pọ̀ àwọn míì farapa
Ileeṣẹ ọmọ ogun Israel ti sọ ṣaaju pe ile kan ti oun gbagbọ pe awọn ọmọ ogun Hamas wa loun sọ ado oloro si, eyii to ṣekupa nnkan bii ogun si ọgbọn lara awọn ọmọ ogun naa.
-
Ilé ẹjọ́ ju akẹ́kọ̀ọ́ 25 láti Fásitì Ajayi Crowther sí ẹ̀wọ̀n lórí ikú akẹẹgbẹ́ wọn
Awọn akẹkọọ Fasiti Ajayi Crowther University ti wọn fi ẹsun ipaniyan kan, ti foju bale ẹjọ
-
Ọgbọ̀n ọjọ́ lòfin là kalẹ̀ fún sísan owó oníbárà báǹkì tó bá wọmi, ṣùgbọ́n ọjọ́ méje la ó fi san tàwọn Heritage Bank - Ọ̀gá àgbà NDIC
O ni eto ayẹwo n lọ lọwọ bayii fun awọn onibara Banki naa gẹgẹ bi ara igbesẹ lati san awọn owo wọn.