Nígbà gbogbo pẹ̀lú rẹ
Ìfilọ́lẹ̀ Túmọ̀ dà bí nínú ògbùfọ̀ aládàáni nínú àpò rẹ.
Ṣé kò sí Íntánẹ́ẹ̀tì bí? Kò sí ìṣòro. Pẹ̀lú ipò àìsílóníforíkorí kódà fóònù rẹ kò ní láti sopọ̀.
Túmọ̀ le ṣèrànwọ́ pẹ̀lú àyọkà tó gùn, àwọn pípè tó lágbára àti kódà àwọn àkọsílẹ̀ tí a fiṣọwọ́.
Sọ̀rọ̀, yàwòrán, kọ tabi tẹ̀wé.
Àṣàyàn rẹ
-
Bá ẹnìkan sọ̀rọ̀ tí ń sọ èdè míràn.
-
Fún àwọn àmì, mẹ́nù, abbl, ṣáà tọ́ka kámẹ́rà rẹ kí o sì gba ìtúmọ̀ kíákíá kan. Kódà o kò nílò ìsopọ̀ Íntánẹ́ẹ̀tì.
-
Fọwọ́kọ àwọn ọ̀rọ̀ àti ẹyọ ọ̀rọ̀ èyítí àtẹ bọ́tìnnì rẹ kò faramọ́.
-
Ṣáà tẹàwọn ọ̀rọ̀ tí o fẹ́ túmọ̀.
